×

Punch Newspapers's video: r K b t : y n M r n- n N n b b l n D r run L ...

@Ọ̀rọ̀ Kàbìtì: Èèyàn Márùn-Ún Nínú Ẹbí Òbílànà Dèrò Ọ̀run Látàrí Oúnjẹ Tí Wọ́n Jẹ | Punch
A dé ilé àwọn mọ̀lẹ́bí Òbílànà láti bá wọn kẹ́dùn àti láti gbọ́ kúlẹ̀kúlẹ̀ ohun tó ṣẹlẹ̀ gan-an tó mú èèyàn márùn-ún nínú mẹ́fà dèrò ọ̀run alákeji lẹ́yìn oúnjẹ tí wọ́n jẹ. A bá ọ̀kan nínú àwọn mọ̀lẹ́bí náà sọ̀rọ̀, a bá ẹnìkan tó jẹ́ ará àdúgbò wọn sọ̀rọ̀ pẹ̀lú, wọ́n sì sọ irú ẹni tí Òbílànà jẹ́ nígbà ayé rẹ̀. A bá aṣojú ilé ìwòsàn ìjọba FMC ti ìlú Abẹ́òkúta náà sọ̀rọ̀, àwọn pàápàá sì bá mọ̀lẹ́bí Òbílànà kẹ́dùn lórí àjálù burúkú náà. -- SUBSCRIBE to our channel: https://bit.ly/3cSYtXf For the latest news, visit our website: https://bit.ly/2T6gh9m Follow PUNCH on: Facebook - https://facebook.com/punchnewspaper Twitter - https://twitter.com/MobilePunch Instagram -https://www.instagram.com/punchnewspa... --

5

4
Punch Newspapers
Subscribers
59.9K
Total Post
2.5K
Total Views
596.1K
Avg. Views
2.4K
View Profile
This video was published on 2022-08-01 19:32:17 GMT by @Punch-Newspapers on Youtube. Punch Newspapers has total 59.9K subscribers on Youtube and has a total of 2.5K video.This video has received 5 Likes which are lower than the average likes that Punch Newspapers gets . @Punch-Newspapers receives an average views of 2.4K per video on Youtube.This video has received 4 comments which are lower than the average comments that Punch Newspapers gets . Overall the views for this video was lower than the average for the profile.Punch Newspapers #family #deaths #hospital has been used frequently in this Post.

Other post by @Punch Newspapers